9
ENGLISH - YORÙBÁ A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z W w (correct formatting of the Yoruba text on this page still in progress) Click here for pdf version of this page wages n owó iÿë, owó, õyà wagon n kêkë çrù waist n ìbàdí, ìdí wait v dúró, dúró dè, dúró tì, retí waiter n adúró tini, agbawó onjç, adìgbàró waiting room n àgbàlá ìdúró dè sì waitress n adúró tini, agbawó onjç, adìgbàró wake v jí, ÿe àìsùn, tají walk n ìrìn walk v rìn, fi çsê rìn wall n ògiri, ìgànná wallet n àpò onjç, àpò owó walnut n àwùsá òyìnbó walrus n irú çranko kan bí ìmàdò wander v rìn kiri, ÿìnà kiri, ÿáko want n (lack) àìní, àbùkù, òfò, àìtó

YORUBA W

Embed Size (px)

DESCRIPTION

Y -W

Citation preview

Page 1: YORUBA W

ENGLISH - YORÙBÁ

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z

W w(correct formatting of the Yoruba text on this page still in progress)

Click here for pdf version of this page

wages n owó iÿë, owó, õyàwagon n kêkë çrùwaist n ìbàdí, ìdíwait v dúró, dúró dè, dúró tì, retíwaiter n adúró tini, agbawó onjç, adìgbàrówaiting room n àgbàlá ìdúró dè sìwaitress n adúró tini, agbawó onjç, adìgbàrówake v jí, ÿe àìsùn, tajíwalk n ìrìnwalk v rìn, fi çsê rìnwall n ògiri, ìgànnáwallet n àpò onjç, àpò owówalnut n àwùsá òyìnbó walrus n irú çranko kan bí ìmàdòwander v rìn kiri, ÿìnà kiri, ÿákowant n (lack) àìní, àbùkù, òfò, àìtówant n (need) fífë, ìfëwant v (desire) fëwant v (need) ÿe àìní, fêfê-kùwar n ogun, ìjàward n (hospital) wöõdù, yàrá gbañgba ilé ìwósánwarden n olùÿô olùtôjú olórí ilé ëkô gíga alábò

Page 2: YORUBA W

wardrobe n (cabinet) ilè ìpamú aÿôwardrobe n (clothes) aÿô wíwöwarehouse n ilè ìpamô ôjàwarm adj gbóná lôwôwôwarmth n ìgbóná ìtaraìfêwarn v ÿe ìkìlõ fúnwarning n ìkìlõwarrant n (law)ìwé àÿç ìmúniìwé ìtìlêhìnìwé ìdánilójú ìwé ëríwarranty n ìwé ìdánilójúwarrior n jagunjagun ögajun ológunwart n wönwònwash n ìwë fíföwash v wë, fö bôwashable adj ÿeé wë ÿeé fösísôdi mímôwasp n agbön, õdç akô oyinwaste n ahoroìdáhoroìparun ínádànùwasteful adj ìnádànùìnákúnàáyàpàwatch n (guard) ëÿô ìÿôwatch n (time) agogo agowatch v (look)wò-ranwatch v (maintain) ÿe àkíyèsíbójútówatch v (observe) ÿô wòwatchful adj níÿöôraÿíÿôtí ó fojúsílëwatchman n olùÿôëÿôôdçwater n omiwater v fún ní omibomiwônbomirinwaterfall n õÿõrö òjò, ìtàkìtì omiwatermelon n èso bàràwatery adj ringbindinwave n (hand) ìjuwôwave n (water) ìrúmiìgbì omiìbilù-omiwave v juwó síwax n ìdaôÿç etíìda oyinödà

Page 3: YORUBA W

way n önà ìrònàwe pron àwa, aweak adj láìlágbáraaláìleraaláìsànláìnípáàárëëweaken v mú-rësô di àilerasô di aláìlágbáraweakness n àileraáìlágbáraàìmókunàìnípáàárëëwealth n owó öröôláwealthy adj lówólôröôlôrölônàweapon n ohun-ìjàohun-ogunohun ílòwear v wölòweather n ojú ôjôojú örunafêfêweave v hunwunwunÿôwun-okùnweb n (spider)ìtakùnaláõtakùnwedding n ìgbéyàwóìsoyigiwedding ring n òrùka ìgbéyàwóWednesday n ôjö kçrin õsêweed n korikoweek n õsê, ôjö méjeweekend n ìparí ösëweekly adj lôsösëlêkan lôsösëweep v ké sôkún dámijéweigh v wön gbé wòfi òÿùwön wön rësílëyëwòweight n ìwönòÿùwönìwúwoweird adj ÿabàmìÿàjèjìwelcome n ìkíniàríyöìkí ayö fún àlejòwell adv lálàfíàní dídá arareresuwöndédéwell n köngaorísun omiwest n ìwô-òrúnìhà yánmàwestern adj níhà ìwô-òrùnwestwards (adv)níhà ìwô-òrùnwet adj rin, tutùwhale n erinmiçja þlánláwharf n èbútéwhat pron kíni?kínlá?èwo?èyítíohun tíwhatever pron ohunkóhunèyíkíyìíèyíwùkóÿe

Page 4: YORUBA W

wheat n àlìkámàôkàwheel n këkêwheelbarrow n këkê ìkêrùwheelchair n këkê alágakëké arôwheeze v mí kankanwhen conj ìgbàtíwhen adv nígbàtínígbàwo?whenever (adv) nígbàkúgbà àní gbàwhere adv ibo? níbo? níbitíwherever adv ibikíbiníbikíbiwhether (conj)ìbáÿeyálàwhich pron/f èwo?èyítíwhich pron/m èwo?èyítíwhich adj tí èyítíwhich pron (neuter)èwo?èyítí

while conj nìwön bíwhile n ìgbà àkókòwhine n híhúkíkùnwhine v húkékùnwhip n ôrë, pàÿán, çgbawhip v lúná lêgbawhisker n kànàngóirun ërëkêirun ëtèwhisper n örö jêjêörö kêlêkêlê òfófówhisper v sõrõ jëjë sõrõ këlëkëlë ÿòfófó fúnwhistle v súfèéwhistle n (object) ìsúfèéwhite n funfunwho pron tani? çnitíwhoever pron çnikêniwhole adj lódidiní dídá arawholesome adj dáradára ní jíjçpéyepíyewhore n àgbèrèaÿêwóödôkôwhose pron ti tani?ti ÷nití

Page 5: YORUBA W

why adv ëêÿe?èétiÿe?nítorí kíni?kílóÿe?kíni ?ìdirë ëêtirí*wick n òwú ìtannáòwú fìtílàwicked adj búburúburú àìláanúìwà ìkàwide adj gbòròjìnnàfëníbòfëgëfëfëgbàràgàdàwidespread adj ìtànkalëìtànkáwidow n opó-bìnrinwidower n opó-kùnrinwidth n ìbú ìbòwife n ìyàwó aya obínrin abilékôwig n irun tí a ÿe fún apárí àkçtë onírun àfôgbônÿeàmì oyè onídájôwiggle v rúnramirawild adj àìtùlójúbí ará igboasôsígbóti ìgbêçhànnàwilderness n aginjù ìgbê ijùwilful adj agídíaÿetinúçnimöômöÿewill n (desire) ìfêìwùwill n (law) ìwé ìhágunàÿçwilling adj ní ìfê sífífêwillingness n ìfêìfê inúÿíÿe tìfêtìfêwilt v rômú rôwin n ìÿëgunwin v ÿêgun, borí jçgbàpawinch n (tool)ërô ìgbé çrù wíwo sókèwind n afêfêòyìëfúùfúwind v yíkàkákáwéwindmill n êrô àfafêfê yíwindow n fèrèséojú afêfêwindpipe n önà öfunwindshield n (windscreen)fèrèsé ojú ôköwindy adj ti afêfêkìkì afêfêní afêfêwine n ôtí òyìnbóôtí èso àjàràwáìnwing n (bird) ìyê apá wing n (airplane)ìnapá ôkö òfúrufúwing n (car)apákan môtò

Page 6: YORUBA W

wink n ìÿêjúdídijú bàìbàììfojúparêwink v ÿêjúdí ojú bàìbàìmójú kúròwinner n/f aÿëgunwinner n/m aÿëgunwinter n ìgbà òtútùwipe v nùnùwire n okùn onírinwisdom n ôgbön, òye, ìmõwise adj gbön, mòye, mõwish v fëwish n ìfêìwùwitch n àjëwitchcraft n iÿç àjê oÿówith prep pëlúàtilôdöbáfidáníwithin adv nínúti inúwithout prep lódelêhìn-òdeláìsíwithstand v dúrótìkôju ìjà sídí-lônà dojúkôkôjú òdì síwitness n/f ëríçlêëríwitness n/m êrí çlëêríwitness v jêëríÿelêëríwolf n ìkokò, kòrikòwoman n obìnrinwomb n inúwonder n ìyanuiÿê-ìyanuèmökísàwonder v ro\ò láìmö dájúdájúrò pëlú iyèméjìwonderful adj yanilênukún fún ìyanu níyànjúwood n igi igbówooden adj onígiwool n irun àgùtànòwúword n örögbólóhùn kanwork n iÿëworkable adj (use)tí ó ÿeéÿeworker n/f òÿìÿêoníÿêworker n/m òÿìÿêoníÿê

Page 7: YORUBA W

workshop n ilé ìÿônàworld n ayéaráyéworm n kòkòròìdinarànworn adj àlògbótí ó bàjêworried adj kúnfún wàhálàkúnfún àníyànworry n wàhálàájòìnira àníyànworry v ÿe làálàáÿe wàhálàworse adj burú jùworship n ìsìn iyìn oyè ôláworship v sìn bu ôlá fún foríbalë jôsìnworst adj burújùlô burú rékôjáworth n iyeìtôsíjámôiyì ìdíyeléìtôyeworthless adj láìtóyeláìníye lóríláìníláríworthy adj nítóyètóyçlókìkíwound n ôgbë, egbòwound v ÿá lögbëwrap v dìbòfi-wéfi-dì rówreckage n ìbàjê ôkörírì ôköwrench n rírôìréwrinkle n ìwunjô ìkíwejeìkátìwrist n ôrùn ôwöwrite v kôköwéhàntúrúwriter n/f akõwéwriter n/m akõwéwriting n ìköwéìwéwrong adj ìÿìnàëbiìÿìÿewrongful adj lásánláìnídìíláìjëbi

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z

Page 8: YORUBA W