32
COERLL - Yorúbà Yémi CC – 2011 The University of Texas at Austin 227 Chapter 10 - Orí K÷wàá | HOME SWEET HOME! OBJECTIVES: In this chapter you will learn: - About ordinals - How to use reflexives - Vowel assimilation, vowel lengthening and vowel deletion - About old and new forms of housing - About your house

Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

  • Upload
    others

  • View
    7

  • Download
    0

Embed Size (px)

Citation preview

Page 1: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

COERLL - Yorúbà Yémi CC – 2011 The University of Texas at Austin 227

Chapter 10 - Orí K÷wàá | HOME SWEET HOME!

OBJECTIVES:

In this chapter you will learn: - About ordinals - How to use reflexives - Vowel assimilation, vowel lengthening and vowel deletion - About old and new forms of housing - About your house

Page 2: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 228 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Àwæn örö (Vocabulary)

Nouns ààfin palace

ab÷ razor

afínjú clean (person)

aláköwé educated person

àtíkè (páúdà) powder

adì÷ chicken

àga onítìmùtìmù sofa

àjà story (house levels)

àlejò guest

amö clay

a«æ ìnura (táwëëlì) towel

àwùjæ a gathering (of people)

àwòrán picture

ayálégbé tenant

balùwë bathroom

búlôökù cement

dìódóráõtì deodorant

èékánná nails

ehoro rabbit

ëdá ènìyàn human beings

fèrèsé/wíñdò window

fôsêëtì faucet

fúláàtì apartment / flat

gbajúmö important

góòlù gold

ibi place

ibùsùn/bêëdì bed

ìdötí dirt

igi ìfæyín/búrôö«ì toothbrush

ìkángun one end of the house

ìká«æsí/kôbôödù closet

ilé ìgbönsë toilet

ìlera good health

Page 3: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 229 CC – 2011 The University of Texas at Austin

ìlú òkèèrè foreign country

ìmôtótó cleanliness

ìpara body lotion

ìrörí pillow

iyanrìn sand

jíígí mirror

kábínêëtì cabinet

kàhìnkàhìn sponge

kápêëtì carpet

kóòmù comb

márà«áná ‘don’t buy matches’ (it's a type of window)

mèremère precious things

mí«ánnárì missionary

mælé-mælé brick layer

ògiri wall

ojúlé room

ægbà yard

öl÷/ ìmêlê laziness

æ«÷ ìfæyín (péèstì) toothpaste

pálö living room

pákò/orín chewing stick

rédíò radio

síìõkì sink

tí«ù tissue

tòlótòló turkey

tôöbù bathtub

Noun Phrases apëërë híhun basket weaving

àsìkòo fôölù fall season

àsìkòo sípíríõgì spring season

àsìkòo sômà summer season

àsìkòo wíñtà winter season

a«æ òkè híhun traditional Yoruba cloth weaving

a«æ pípa láró tie-dying

ènìyàn mímö familiar face

Page 4: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 230 CC – 2011 The University of Texas at Austin

÷ní híhun mat weaving

÷yìn fífö palm oil extraction

igun ilé one angle/corner of the house

ilé alámö brick house

ilée onísìmêõtì house built with cement

ilé ìgbönsë toilet

ìlëkë sínsín bead-making

ìyá àgbà old woman

omi gbígbóná hot water

omi tútù cold water

æ«÷ ìfæwô hand soap

æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo

æ«÷ ìwë bath soap

Verb kórira to dislike

Verb Phrases têpá mô«ê to be hardworking

Adjectives têjú spacious

tónítóní stainless

Page 5: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 231 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Lesson 1 - Ëkô Kìíní

Ordinals Remember in Chapter Four, Lesson 1, we compared numbers and cardinals as found below:

Numbers Cardinals English

oókan kan one

eéjì méjì two

÷êta mêta three

÷êrin mêrin four

aárùnún márùnún five

÷êfà mêfà six

eéje méje seven

÷êjæ mêjæ eight

÷êsànán mêsànán nine

÷êwàá mêwàá ten

oókànlá môkànlá eleven

eéjìlá méjìlá twelve

(where eéjìlá implies ‘twelve’ and ìwé méjìlá implies ‘twelve books’)

Ordinals

ìkíní first

ìkejì second

ìk÷ta third

ìk÷rin fourth

ìkarùnún fifth

ìk÷fà sixth

ìkeje seventh

ìk÷jæ eighth

ìk÷sànán ninth

ìk÷wàá tenth

ìkækànlá eleventh

ìkejìlá twelfth

Page 6: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 232 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Like cardinals, ordinals are placed after their nouns. However, since vowel deletion is very common in Yorùbá language, the initial / i / of the ordinal is deleted when the above ordinals are used as qualifiers as found below.

For example:

Ordinals

æjô kìíní first day

æjô k÷rin fourth day

æjô k÷rìnlá fourteenth day

æjô karùndínlógún fifteenth day

æjô k÷rìndínlógún sixteenth day

æjô k÷tàdínlógún seventeenth day

æjô kejìdínlógún eighteenth day

æjô kækàndínlógún nineteenth day

ogúnjô twentieth day

The table below compares the numbers to the cardinals, and the cardinals to the ordinals.

Numbers Cardinals Ordinals

oókan kan ìkíní

eéjì méjì ìkejì

÷êta mêta ìk÷ta

÷êrin mêrin ìk÷rin

aárùnún márùnún ìkarùnún

÷êfà mêfà ìk÷fà

eéje méje ìkeje

÷êjæ mêjæ ìk÷jæ

÷êsànán mêsànán ìk÷sànán

÷êwàá mêwàá ìk÷wàá

oókànlá môkànlá ìkækànlá

eéjìlá méjìlá ìkejìlá

Page 7: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 233 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 1 Kí ni àwæn æjô wönyí ni Yorùbá? Provide the Yorùbá equivalents of the following.

Bí àp÷÷r÷:

7th day = Æjô keje

1. 21st day =

2. 15th day =

3. 6th day =

4. 18th day =

5. 3rd day =

6. 11th day =

7. 2nd day =

8. 50th day =

9. 37th day =

10. 1st day =

Page 8: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 234 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 2 Dáhùn àwæn ìbèérè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences.

1. Æjô wo ni æjô kìíní o«ù k÷ta ædún yìí?

2. Æjô wo ni æjô kejìdínlógún o«ù kejì ædún yìí?

3. Æjô wo ni æjô kækàndínlógún o«ù k÷rin ædún yìí?

4. Æjô wo ni æjô kejìlá o«ù k÷fà ædún yìí?

5. Æjô wo ni æjô k÷tàlélógún o«ù k÷jæ ædún yìí?

Page 9: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 235 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 3 Kæ àwæn æjô wönyí ní Yorùbá. Write the following dates in Yorùbá.

Bí àp÷÷r÷:

1st January

æjô kìíní, o«ù kìíní ædún

1. 17th September

2. 21st November

3. 9th July

4. 31st March

5. 11th April

6. 23rd May

7. 18th October

8. 3rd August

9. 10th June

10. 20th February

Page 10: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 236 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 4 Kæ àwæn æjô ösë wönyí ní Yorùbá. Write the following days of the week in Yorùbá (using the workday system).

Bí àp÷÷r÷:

Æjô kìíní ösë = Æjô ajé

1. Æjô kéjì ösë =

2. Æjô kêta ösë =

3. Æjô kêrin ösë =

4. Æjô karùnún ösë =

5. Æjô k÷fà ösë =

6. Æjô keje ösë =

I«ê »í«e 5 So àwæn tí ó bara mu ni öwô A àti öwô B papö. Match the words in column A with those in column B.

A B

æjô ÷tì Sunday

æjô abámêta Monday

æjôbö Friday

æjôrú Saturday

æjô ì«êgun Thursday

æjô àìkú Wednesday

æjô ajé Tuesday

Page 11: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 237 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 6 So àwæn tí ó bara mu ni öwô A àti öwô B papö. Match the words in column A with those in column B.

A B

Ogún òkè 6 books

Ædún kejìlá 12 years

Ìwé mêfà 20 floors

Òkè ogún 6th book

Ædún méjìlá 12th year

Ìwé k÷fà 20th floor

Page 12: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 238 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Lesson 2 - Ëkô Kejì:

Reflexives - Vowel Assimilation,

Vowel Lengthening, and Vowel Deletion

Reflexives denote what you do by yourself or for yourself as opposed to someone doing it for you. In order to state the former, you use ‘fúnrara’ followed by a possessive pronoun as found below:

fúnraraà mi fúnraraa wa

fúnraraà r÷ fúnraraa yín

fúnraraa rë fúnraraa wæn For example: Mo ya irunùn mi fúnraraà mi. I combed my hair myself. Compare to: Màmáà mi ya irunùn mi fún mi. My mother combed my hair for me. Or Màmáà mi bá mi ya irunùn mi. My mother helped me comb my hair.

I«ê »í«e 1 Parí àwæn gbólóhùn wönyìí. Complete the following sentences with the appropriate reflexive.

1. Èmi ñ wë

2. Òun ñ fæ ÷nu

3. Àwa ñ para

4. Àwæn ñ bôjú

5. Ó ñ fæ eyín

6. Mò ñ ya irun

7. À ñ fæ ojú

8. Àwæn ækùnrin ñ fá irùgbön

9. Àwæn obìnrin ñ kun ètè

10. Wôn ñ fæ æwô

Page 13: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 239 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 2 »e àwæn nõkan wönyì. Demonstrate the following gestures. 1. Mo ñ fæ eyìnìn mi fúnraraà mi. 2. O ñ ya irunùn r÷ fúnraraà r÷. 3. Ó ñ fá irùngbönæn rë fúnraraa rë. 4. A ñ fæ æwæ wa fúnraraa wa. 5. ¿ ñ pa ara yín fúnraraa yín. 6. Wôn ñ nu æwôæ wæn fúnraraa wæn.

I«ê »í«e 3 Lo àp÷÷r÷ yìí láti fi dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Use this example to answer the following questions.

Bí àp÷÷r÷:

Túndé/ eyín Túndé, fæ eyínìn rë fúnraraa rë. Kí ni ò ñ «e? Mò ñ fæ eyínìn mi fúnraraà mi.

1. Tádé/ wë ara. 2. Ögbêni Adé/ fæ a«æ. 3. Kêmi àti Títí /ya irun. 4. Ìwæ/ nu ara (conversational context). 5. Èmi/ pa ara. 6. Omidan Òdú«ælá/ fæ æwô. 7. Öjögbôn Owólabí/ ka ìwé. 8. Ìwæ àti Títí/ j÷ oúnj÷ (conversational context). 9. Ìwæ àti Títí/ j÷ oúnj÷ (non-conversational context). 10. Tósìn/ se oúnj÷.

Page 14: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 240 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Expressions such as ojoojúmô, ösöösán, alaalê, ædæædún etc. indicate what one does every time. For example, ædún means year. However, ædæædún implies every year.

ojúmô (day) àárö (morning) ösán (afternoon) alê (night) o«ù (month) ösë (week) ædún (year)

ojoojúmô (every day) àràárö (every morning) ösöösán (every afternoon) alaalê (every evening) o«ooo«ù (every month) ösöösë (every week) ædæædún (every year)

I«ê »í«e 4 Ó kàn ê. Sæ fún wa àwæn nõkan tí o máa ñ «e lójoojúmô. It’s now your turn. Tell us what you do everyday.

Bí àp÷÷r÷:

Láràárö tí mo bá jí, mo máa ñ wë. Lêyìn náà, mo máa ñ fæ eyínìn mi. Lêyìn tí mo bá fæ eyínìn mi tán, mo máa ñ……….. lösöösán, mo máa ñ………..

I«ê »í«e 5 Fi örö tí ó bá y÷ dí àwæn àlàfo yìí Fill in the spaces with appropriate words.

____________ tí mo bá jí ni mo máa ñ wë. »ùgbôn ní ____________ n kò lè «aláì má j÷

oúnj÷ ösán. Kì í «e pé mo fêràn oúnj÷ púpö àmô, n kì í fi oúnj÷ alêë mi «eré ní

____________. Fún a«æ ösë kan, ____________ ni mo máa ñ fæ àwæn a«æö mi nítorí pé n

kò ní ààyè láàrin ösë, «ùgbôn ____________ ni mo máa ñ ra a«æ tunun fún ilé-ìwée mi.

Page 15: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 241 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Cultural Vignette: Ìmôtótó

Àwæn Yorùbá jê afínjú ènìyàn. Wôn kórìrá ìdötí ganan ni. Wôn gbàgbô pé bí ènìyàn kò tilë lówó lôwô láti fi ra orí«irí«i à«æ ìgbàlódé, ìwönba nõkan tí ènìyàn bá ní, kí ènìyàn «e ìtôjú rë kí ó mô tónítóní. Wôn gbàgbô pé kí ènìyàn jí ní òwúrö kí ó fæ eyínin r÷ kí ó dá «áká, kí ó gé èékánná rë, kí ó wë, kí ó tôjú irunun rë, kí ó sì wæ asæ tí ó mô kí ó tó dábàá láti pé pëlú àwæn ènìyàn láwùjæ. Ìdí nìyí tí wôn fi máa ñ pa á lówe pé ‘Wömbö wæmbæ kô leyín, béyín bá «e méjì kí ó «á à funfun’. Èyí túmö sí pé ìmôtótó se pàtàkì fún omælúwàbí. Àwæn Yorùbá gbàgbô pé tí ènìyàn bá jê onímöôtótó nípa títôjú araa wæn, àìsàn àti ààrùn yóò jìnnà réré sí sàkání onítöhún. Wôn tún ní ìgbàgbô pé ìmôtótó ñ «okùnfà ìlera tó péye. Wôn á ní ÷ni tó ní ìlera ló lóhun gbogbo. Fún àwæn Yorùbá, ìlera lærö fún ohun gbogbo. Àwæn Yorùbá máa ñ kæ orí«irí«i orin nípa ìmôtótó láti kô àwæn æmææ wôn ní ì«e pàtàkì ìmôtótó. Bí àp÷÷r÷:

‘Ìmôtótó ló lè «êgun àrùn gbogbo (2x)

Ìmôtótó ilé, ìmôtótó ara, ìmôtótó oúnj÷

Ìmôtótó ló lè «êgun àrùn gbogbo’.

àti

‘Wë kí o mô

Gé èékánná r÷

J÷un tó dára lásìkò

Má j÷un jù’.

Nítorí àwæn orí«ì ëkô pàtàkì báyìí, àwæn æmædé mö pé tí wôn bá jí ní öwúrö, balùwë ni ibi àkôkô tí wôn gbôdö læ láti læ tôju araa wæn kí wôn tó «e ohunkóhun. Ìmôtótó «e pàtàkì fún ëdá ènìyàn.

Page 16: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 242 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 6 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences.

1. Kí ni ìdí tí àwæn Yorùbá fi kórira ìdötí? 2. Irú ènìyàn wo ni àwæn Yorùbá jê? 3. Kí ni ìrètí àwæn Yorùbá pé kí ènìyàn kôkô «e ní òwúrö tí ó bá jí? 4. Àõfààní wo ní ìmôtótó ñ «e fún àwæn ènìyàn? 5. Kí ni pàtàkì ëkô nípa ìmôtótó fún àwæn æmædé ní ilë÷ Yorùbá? Kí ni èrò r÷ nípa orin yìí

“Wë kí o mô…?

I«ê »í«e 7 Kæ ìtumö àwæn örö wönyí sílë ní èdèe Yorùbá. Write down the meanings of these words in Yorùbá.

1. ìmôtótó 2. kórira 3. ìlera lærö 4. à«æ ìgbàlódé

I«ê »í«e 8 Kæ ewì kan ní èdèe Yorùbá tí ó j÷ mô ìmôtótó ní ìlúu r÷ Write a poem about cleanliness in your country.

I«ê »í«e 9 Sæ 'bêë ni ' tàbí 'bêë kô' fún àwæn gbólóhùn wönyí. State whether the following sentences are true or false.

BÊË NI BÊË KÔ

1. Àwæn Yorùbá fêràn ìdötí. ☐ ☐

2. Àwæn Yorùbá kò ní ìgbàgbô nínú eyín funfun. ☐ ☐

3. Òtítô ni pé ìlera ni ærö. ☐ ☐

4. Orin kíkæ kì í «e önà kan láti kô àwæn æmæ ní ëkô. ☐ ☐

5. Tí àwæn Yorùbá bá ti jí, oúnj÷ ni wôn kôkô máa ñ j÷. ☐ ☐

Page 17: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 243 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 10 So àwæn tí ó bara mu ni öwô A àti öwô B papö. Match the words in column A with those in column B.

A B

Ìmôtótó belief

ìdötí health

ìlera illness

ìgbàgbô cleanliness

àrùn dirt

Vowel Assimilation

This is a phonological process by which one vowel assimilates into the other when they are contiguous. In A below, the process by which the first vowel (V1) assimilates into the next vowel (V2), or the second vowel (V2) in C assimilates into the first vowel (V1) is known as vowel assimilation.

A B

V1 V2

kú ilé kúulé a greeting to welcome someone into the house

kú ìrölê kúùrölê good (early) evening

C D

V1 V2

kú àárö káàárö good morning

Ojú irin ojúurin railroad

Æjà Æba Æjàaba the name of a market in Ìbàdàn city, Nigeria

Assimilation can be either progressive V1 + V2 V1V1 in which case kú + ilé kúuié, or regressive V1+V2 V2V2 as in kú + alê káalê.

Page 18: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 244 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Vowel Lengthening

Vowel lengthening occurs when a vowel is duplicated vowel. The assimilation of one vowel by another vowel across word boundaries results in vowel lengthening as in most of B and D above.

Vowel lengthening occurs at vowel + consonant word boundaries in a possessive relationship such as ilée bàbá (bàbá's house). However, vowel lengthening is unnecessary when it is V+V as in ilé ìyá (ìyá's house), which means that vowel lengthening does not necessarily occur because of contiguity of vowels. Examples of vowel lengthening are found in F below wherethe final vowels of i lé and ajá become lengthened.

The parti t ive t i

The genitival particle ‘ti’ occurs before a noun or a pronoun as in the following examples:

E F

Ilé ti örê ìlée törê friend’s house

Ajá ti àwa ajáa tiwa our dog

The final vowel in Ì lé and ajá before the partitive becomes lengthened in column F above.

Vowel lengthening also occurs when a vowel is duplicated as in the following examples of third person singular object pronouns following their verbs:

mo rí i I saw it

ó j÷ ê s/he ate it

ó tú u s/he untied it

Adé bó o Adé peeled it

Vowel Deletion/Vowel Contraction

Vowel deletion is a product of vowel contraction. Vowel deletion is a step in the phonological process of vowel contraction not assimilation. Assimilation and contraction are two different phonological processes. In the case of vowel contraction, when two vowels are in contiguous relationship across word boundaries, one of them is deleted and the two words contract to become one.

Page 19: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 245 CC – 2011 The University of Texas at Austin

ti örê törê that of a friend(a friend’s)

ti àwa tàwa that of ours(ours)

rí ÷ja rêja to see fish

ta i«u ta«u to sell yam(s)

ra ÷ran r÷ran to buy meat

Vowel deletion can occur without contraction when it is not across word boundaries as in the following examples: Adéælá Déælá Æládépò Ládépò

I«ê »í«e 11 Vowel lengthening (VL) or vowel contraction (VC)? Write out the complete words.

Bí àp÷÷r÷:

Kun ojú kunjú (VC)

1. pa ara

2. bô ojú

3. se ÷ja

4. kú ìrölê

5. ilé ijó

6. æmæ i«ê

7. gé igi

8. fæ ÷nu

9. wæ a«æ

10. gun igi

Page 20: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 246 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Lesson 3 - Ëkô K÷ta:

Our House

ILÉ ALÁMÖ ÀTI ILÉE SÌMÊÕTÌ

Ní ilë÷ Yorùbá, orí«i ilé méjì ni ó wà: ilé alámö àti ilé oní sìmêõtì. Ilé alámö jê ilé tí ó wà kí aláyé tó dáyé. Àwæn òyìnbó aláwö funfun ni wôn gbé ilée búlôökù wá. Ilé alámö wôpö ní oko àti ilú kékeré. Ilée símêõtì ni ènìyàn sáábà máa ñ rí tí ènìyàn bá læ sí àwæn ìlú ñlá bíi Èkó àti Ìbàdàn. Erùpë amö pupa àti omi ni wôn pò pö láti fi kô ilé alámö. Mælémælé ni orúkæ àwæn tí ó mö nípa bí wôn «e ñ kô ilé alámö. Púpö nínú ilé alámö ni wôn máa ñ ní fèrèsé tí wôn ñ pè ní ‘márà«áná’. Fèrèsé náà máa ñ kéré ganan ni. Púpö nínú ilé alámö ni wæn kì í ní ilé ìgbönsë. Nítorí ìdí èyí ni àwæn aláköwé kì í fi í gbé ibë.

Àwæn òyìnbó aláwö funfun ni wôn mú à«àa kíkô ilée sìmêõtì wá. Sìmêõtì àti iyanrìn ni wôn sì máa ñ lo láti fi kô ilée sìmêõtì. Ilé tí wôn fi sìmêõtì kô máa ñ ní agbára ju ilé alámö læ nítorí pé sìmêõtì àti iyanrìn ní agbára láti mú ilé dúró. Ilée sìmêõtì wôpö ní àwæn ilú ñlá bíi Ò«ogbo, Ìbàdàn, Èkó, Ilé-Ifë àti bêë bêë læ. Ilé alámö kì í sáábà ní àjà nítorí pé kò ní agbára bí ilée sìmêõtì.

I«ê »í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences.

1. Orí«i ilé mélòó ni ó wà ní ilë÷ Yorùbá? 2. Dárúkæ àwæn ilé náà. 3. Níbo ni ilé alámö wôpö sí? 4. Báwo ni ilé tí wôn fi sìmêõtì kô «e dé ilë÷ Yorùbá? 5. Àwæn ohun-èlò wo ni a nílò láti fi kô ilé alámö? 6. Kí ni ìdí rë tí àwæn aláköwé kì í fí gbé ilé alámö? 7. Kí ni orúkæ tí àwæn ènìyàn máa ñ pe àwæn tí wôn ñ kô ilé? 8. Kí ni àwæn ohun-èlò tí wôn máa ñ lò fún ilée sìmêõtì? 9. Sæ ìdí rë tí wôn fi máa ñ fi sìmêõtì àti iyanrìn kô ilé lóde-òní. 10. Báwo ni àwæn fèrèsé ilé oní sìmêõtì «e yàtö sí ti alámö?

Page 21: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 247 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 2 Mú èyí tó y÷ nínú àwæn wönyí sí ibi tó y÷ gêgê bí o «e rí i kà nínú àyækà òkè yìí. Check the appropriate category for the following expressions according to the text (ILÉ ALÁMÖ ÀTI ILÉE SÌMÊÕTÌ) above.

I lé alámö Ilée sìmêtì

1. Yorùbá ☐ ☐

2. Àwæn òyìnbó ☐ ☐

3. Búlôökù ☐ ☐

4. Oko àti ìlú kékeré ☐ ☐

5. Erùpë amö pupa ☐ ☐

6. Mælémælé ☐ ☐

7. Iyanrìn ☐ ☐

8. Àjà ☐ ☐

9. Agbára ☐ ☐

10. Èkó àti Ìbàdàn ☐ ☐

I«ê »í«e 3 Kæ ìtumö àwæn örö wönyí sílë ní èdèe Yorùbá. Write down the meanings of these words in Yorùbá.

1. búlôökù 2. erùpë amö pupa 3. mælémælé 4. iyanrìn 5. àjà

Page 22: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 248 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 4 Sæ bêë ni tàbí bêë kô fún àwæn gbólóhùn wönyìí. State whether the following sentences are true or false.

BÊË NI BÊË KÔ

1. Orí«i ilé méjì ni ó wà: ilé alámö àti ilée pako. ☐ ☐

2. Ilé alámö wôpö ní ilú ñlá ñlá. ☐ ☐

3. Èrùpë amö pupa àti omi ni wôn fi ñ kô ilée sìmêõtì. ☐ ☐

4. Gbogbo ilé alámö lo ní ilé ìgbönsë ☐ ☐

5. Ilé tí wôn fi sìmêõtì kô máa ñ ní agbára ju ilé alámö læ. ☐ ☐

I«ê »í«e 5 Parí àwæn gbólóhùn wönyí. Complete the following questions. 1. Ilée wôpö láàrin àwæn Yorùbá. 2. Àwæn ni wôn gbé à«à ilée sìmêêõtì wá. 3. Ilée ___________________ ní agbára ju ilée læ. 4. Àwæn __________________fêràn láti máa gbé ilée . 5. àti __________________ni wôn fi ñ kô ilé alámö.

Cultural Vignette: I lé Olókè

Orí«irí«i àjà ni àwæn ilé máa ñ ní ní ilë÷ Yorùbá. Púpö nínú àwæn ilé tí wôn wà ní oko àti ìgbèríko ni ó máa ñ ní àjà kan. Àwæn ilé tí ó wà ní ìlú títóbi bíi Èkó, Ìbàdàn, Ab÷òkúta, Àkúrê, Adó-Èkìtì àti bêë bêë læ máa ñ ní àjà méjì, mêta àti bêë bêë læ. Àwæn òyìnbó aláwö funfun ló mú à«à ilé alájà méjì wà sí ilë÷ Yorùbá. Gêgê bíi àwæn akötàn ti sæ, ìlúu Bàdágírì ni wôn kôkô kô ilé olókè méjì sí. Ó lé lôgôrùnún ædún sêyìn tí wôn kô ilé yìí. Àwæn òyìnbóo Mí«ánnárì ni wôn kô ilé alájà méjì náà. Ní ìlú Ìbàdàn, àdúgbòo Kúd÷tì ni wôn kôkô kô ilé olókè méjì sí. Ilé olókè jê ilé tí ó wôn láti kô. Àwæn ènìyàn pàtàkì ní àwùjæ ni wôn ní owó àti agbára láti kö ilé olókè méjì ní ilë÷ Yorùbá.

Page 23: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 249 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 6 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences.

1. Orí«i àjà mélòó ni àwæn ilé máa ñ ní ní ilë÷ Yorùbá? 2. Àjà mélòó ni àwæn ilé tí ó wà ní ìlú títóbi bíi Èkó, Ìbàdàn, Ab÷òkúta, Àkúrê, Adó-Èkìtì àti

bêë bêë læ máa ñ ní? 3. Níbo ni wôn kôkô kô ilé olókè méjì sí? 4. Ìgbà wo ni wôn kô ilé olókè méjì yìí? 5. Àwæn òyìnbó wo ni ó kô ilé alájà méjì náà?

I«ê »í«e 7 Sæ bêë ni tàbí bêë kô fún àwæn gbólóhùn wönyí. State whether the following sentences are true or false.

BÊË NI BÊË KÔ

1. Ilé alájà jê à«à ìlú òkèèrè. ☐ ☐

2. Àwæn ilé tí ó wà ní ìlú kékeré máa ñ ní àjà púpö. ☐ ☐

3. Ìlú Èkó nìkan ni à«à ilé alájà púpö wá. ☐ ☐

4. Àwæn Hausa ni wôn mú à«à ilé alájà kíkô wa. ☐ ☐

5. Ìlú Ëpê ni wôn kôkô kô ilé olókè méjì sí. ☐ ☐

6. Àwæn òyìnbó Köríà ni wôn kô æ. ☐ ☐

7. Ó ti tó ægôrùnún ædún tí wôn kô ilé olókè ní ilë÷ Yorùbá. ☐ ☐

8. Àwæn òyìnbó mí«ánnárí ni wôn kô ilé alájà méjì náà. ☐ ☐

9. Ilé olókè jê ilé tí kò wôn láti kô. ☐ ☐

10. Àwæn gbajúmö láwùjæ nìkan ni wôn lè kô ilé alájà púpö. ☐ ☐

Page 24: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 250 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 8 Wá àwæn örö wönyí.

Look for these words in the puzzle below. Pay attention to the tones! ààfin‚ afínjú‚ àjà‚ aláköwé‚ ayálégbé‚ ehoro‚ fèrèsé‚ góòlù‚ ibùsùn‚ ìdötí

I«ê »í«e 9 Kæ ìtumö àwæn örö wönyí sílë ní èdèe Yorùbá. Write down the meanings of these words in Yorùbá.

1. ìgbèríko 2. à«à 3. akötàn 4. òyìnbóo Mí«ánnárì 5. ènìyàn pàtàkì

à à f i n a g b a f i n j u j

i g b a ñ l a d f g i a d e a

a g ó ò l ù a d a è a i g o g

y l í ö à i o l ö y r y a l u

á è á ì p j g n á g a è a k d

l á k k ì ö à ì í k b l s b i

é l j u ö d l á b b ö ö e é u

g d è á h w ö e l ù e w n g í

b ö a d o o é t h á s Í a m b

é s e a r è r á í o w ù y j u

d a g o o l u ì b d r á n a à

a l a w a d I l d a e o d i w

i f I b u s u n o ö l d i e y

f è r è s e g o o d t e e d í

a f í n j ú á y a l à a f i n

Page 25: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 251 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Örö àdásæ (Monologue)

Fúláàtì àbúròo màmáà mí ækùnrin

Ní ilë÷ Nàìjíríà, àpátímêëõtì ni àwæn Yorùbá máa ñ pè ní fúláàtì. Tí àwæn ènìyàn kò bá tí ì «etán láti kô ilé, wôn máa ñ rêõtì àpátímêëõtì láti gbé. Àwæn aláköwé ni wôn sáábà máa ñ gbé fúláàtì. Àbúrò màmáà mi j÷ agb÷jôrò ní ìlú Ìbàdàn. Wôn sì rêõti fúláàtì kan sí Bódìjà Tuntun. Orúkæ wæn ni Læya Adébímpé. Fúláàtì wæn tóbi ganan ni. Ó ní pálö ñlá méjì àti yàrá ìbùsùn mêrin. Yàrá tí ó tòbi jù ni yàrá àbúrò màmáà mi àti ìyàwóo wæn. Yàrá yìí ní baluwë àti ilé ìyàgbê tirë lôtö. Balùwë àti ilé ìyàgbê kan tó kù wà fun àwæn æmæ àti àwæn àlejò. Ènìyàn kò lè «àdédé wæ fúláàtì àbúròo màmáà mi láì «e pé ó jê ÷ni mímö. Ìdí nìyí tí o fí jê pé ìta gbangba ni wôn ti máa ñ gbàlejò. Tí ó bá «e ènìyàn mímö ni ó wá kí àwæn ìdílé àbúròo màmáà mi, pálö tí ó wà ní iwájú ni wôn máa jókòó sí láti bá wæn sörö àti «eré. »ùgbôn tí ó bá «e àlejò pàtàkì ni, pálö ñlá kejì ní wôn máa ti ñ gbàwôn lálejò. Pálö ñlá yìí tóbi bíi ààfin Æba. Wôn sí tún «e é lô«öô lórí«irí«i pëlú àwæn ohun mèremère bí i góólù. Kódà kò yàtö sí àafin. Ìdí nìyí tó fi jê pé àwæn àlejò pàtàkì nìkan ni wôn máa ñ gbà láàyè láti jókòó níbë. Æmæ méjì péré ni àbúròo màmáà mi bí – Adébôlá àtí Adébóyè. Ækùnrin àti obìnrin ni wôn. Adébôlá ñ lo yàrá kan. Adébóyè náà sì ní yàrá tirë. Yàrá kan tókù ni yàrá àlejò. Fúláàtì àbúrò màmáà mi tóbi gan-an ni. Öpölæpö ènìyàn ni wôn máa ñ sæ pé ó wu àwæn. Ìta gbangbaa wôn têjú, ó sì láàyè tó pö. Ohun tó wù mí jùlæ nípa fúláàtì àbúrò màmáa mi nipé wôn fi ægbà yiká tó fi jêpé àwæn ènìyàn tí wôn ñ læ níta kò le rí ohun tí ó ñ læ nínúu fúláàtì àbúrò màmáà mi.

Page 26: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 252 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 10 Dáhùn àwæn ìbèérè wönyí ní ëkúnrêrê. Answer the following questions in complete sentences.

1. Ta ni wôn ñ sörö nípa fúláàtì rë nínú nõkan tí a kà? 2. Irú i«ê wo ni wôn ñ «e? 3. Níbo ni fúláàtì tí a sörö rë wà ní ìlú Ìbàdàn? 4. Báwo ni a «e «e àpèjúwe fúláàtì náà? 5. Ta ni ó ñ lo yàrá tí ó tóbi jù nínúu fúláàtì yìí? 6. Kí ni o rò pé ó jê ìdí rë tí Læya Adébímpé kì í fí gba àwæn ènìyàn láàyè láti wælé láì «e pé

wôn jê ÷ni mímö? 7. Irú àwæn ènìyàn wo ni wôn le wæ pálö ñlá kejì? Kí ni ìdí èyí? 8. Æmæ mélòó ni Læya Adébímpé bí? Kí ni orúkææ wæn? 9. Yàrá mélòó ni wôn ñ lò? 10. Kí ni ÷ni tí ó ñ sörö nípa Læya Adébímpé fêràn jùlæ nípa fúláàtì yìí? Báwo ni ÷ni náà «e jê

sí Læya Adébímpé?

I«ê »í«e 11 Sæ bêë ni tàbí bêë kô fún àwæn gbólóhùn wönyí. State whether the following sentences are true or false.

BÊË NI BÊË KÔ

1. Àpátímêëõtì ni àwæn Yorùbá máa ñ pè ní fúláàtì ☐ ☐

2. Ëgbônæn màmáà mi jê agb÷jôrò ní ìlú Ìbàdàn. ☐ ☐

3. Pálö ñlá méjì àti yàrá ìbùsùn mêta ni ó wà ní fúláàtì àbúrò màmáà mi

☐ ☐

4. Ènìyàn lè «àdédé wæ fúláàtì àbúròo màmáà mi. ☐ ☐

5. Æmæ kan péré ni àbúròo màmáà mi bí ☐ ☐

Page 27: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 253 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 12 Parí àwæn gbólóhùn wönyí. Complete the following sentences.

1. Àwæn ___________ ni wôn máa ñ gbé àpátímêëõtì. a. aláköwèé b. àgbë c. æd÷ d. àgbàlagbà

2. _______________ ni àwæn Yorùbá máa ñ pè ní fúláàtì. a. Ilé olókè b. Ilé onílë c. Àpátímêëõtì d. Fúláàtì

3. I«ê _____________ni àbúrò Màmáà mi ñ «e. a. aláköwèé b. àgbë c. æd÷ d. agb÷jôrò

4. Àbúròo màmáà mi ñ gbé ní àdúgbòo ______________? a. Môkôlá b. B÷÷r÷ c. Bódìjà Tuntun d. Bódìjà Àtijô

5. Æmæ ___________ ni àbúròo màmáà mi bí? a. mêfà b. méjì c. mêrin d. márùnún

Page 28: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 254 CC – 2011 The University of Texas at Austin

Lesson 4 - Ëkô K÷rin

Our House

Örö àdásæ (Monologue)

I lée wa (Our house)

Ilée wa jê ilé alájà méjì. Öpölæpö ojúlé ni ilé yìí ní. Àjà kìíní ní yàrá mêjæ, bêë sì ni àjà kejì ní yàrá mêjæ pëlú. Bàbáà mi fi gbogbo yàrá mêjëëjæ tí ó wà ní àjà kìíní rêõtì fún àwæn ayálégbé. Àwæn ìdílé mêrin ötöötö ni wôn gba àjà kìíní ní yàrá méjì–méjì. Wôn fi yàrá kan «e yàrá ìbùsùnun wæn. Ilé ìdáná méjì, balúwë méjì àti ilé ìyàgbê méjì ni ó wa ní àjà kìíní. Àwæn ayalégbé sì pín wæn ní ìdílé méjì sí balúwë, ilée ìdáná àtí ilée ìyàgbê köökan. Yàrá mêjæ ni ó wà ní àjà kejì «ùgbôn èmi àti àwæn òbíì mi pëlú awæn ëgbôn àti àbúròò mí nìkan ni à ñ gbé ní àjà kejì. A ní pálö ñlá kan tí a ti máa ñ gba àlejò. A sì tún ní pálö kékeré tí awa æmæ ti máa ñ «eré, tí a sì ti máa ñ wo t÷lifí«àn. Bàbáà mi ní yàráa ti wæn tí ó ti pálö ñlá. Yàrá ìyáà mi sì tëlé ti bàbáà mi. Ëgbônön mi ækùnrin tí ó wà ní Yunifásítì ti Æbáfêmi Awólôwö ní llé-Ifë ní yàrá tiwæn lôtö, ó sì súnmô pálö ti àwa yòókù. Yàrá àwæn æmæ ækùnrin méjì yòókù àti ti awa obìnrin wà ní ìkangun ilé. Yàrá ìyáàgbà ni ó tëlé ti ìyáa mi. Gbogbo yàrá tí ó wà ní àjà kejì ni àwæn ÷bíi mi ñ gbé tó bêë gê tí ó fi jê wípé kò sí àyè fún ayálégbé kankan láti gbé pëlúu wa. Yàrá ìdáná méjì, balúwë méjì àtì ilé ìyàgbê méjì ni ó wà ní àjà kejì bí ó ti wà ní àjà kìíní. »ùgbôn àwæn ÷bí mi nìkan ni wæn ñ lo gbogbo àwæn yàrá wönyí. Eléyìí fún wa láàyè púpö láti rí ibi kó ÷rù sí. Kódà ìyáa mi ráàyè sin nõkan ösìnin wæn bíi adì÷, ehoro àti tòlótòló. Bàbáà mi fi ægbà yí ilée wa ká. Eléyìí sì fún àwa æmædé láñfààní láti «ere sí ibi tí ó bá wùwá nínú ægbàa wa. Ægbà ilée wa tóbi gan-an ni, ó sì têjú púpö.

Page 29: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 255 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Answer the following questions in complete sentences.

1. Àjà mélòó ni ilé tí a ká nípa rë ní? 2. Àwæn ayálégbé mélòó ni wôn ñ gbé ilé yìí? 3. Pálö mélòó ni ayálégbé köökan ní? 4. Yàrá mélòó ni ó wà ní gbogbo àwæn àjà tí ilé náà ní? 5. Pálö mélòó ni àwæn onílé ní? 6. Níbo ni yàrá ìyáàgbà wà? 7. Balùwë mélòó ni gbogbo àwæn ayálégbé ñ lò? 8. Kí ló dé tí àwæn ayálégbé kankan kò fi le gbé pëlú àwæn onílé ní àjà ti wæn? 9. Kí ló dé tí àwæn æmædé fi le «eré sí ibi ti ó wù wôn ní ilé yìí? 10. Kí ni ìdí tí àyè fi gba ìyá láti sin nõkan ösìn? Dárúkæ àwæn õnkan ösìn yìí.

I«ê »í«e 2 Parí àwæn gbólóhùn wönyí. Complete the following questions.

Ilée wa jê ilé alájà ____________. Àwæn ayálégbé ____________ ni wæn wà ní ilée wa.

Gbogbo àpapö yàráa tí ò wà ní ilée wá jê ____________. ____________ mi ækùnrin tí ó wà

ní Yunifásítì ti Æbáfêmi Awólôwö ní llé-Ifë ní yàráa tiwæn lôtö nítorí pé a ní yàrá tí ò pö. Kódà,

màmáa mi ní àõfààní láti sin àwæn nõkan æsìn wæn bí i ____________, ____________ àti

____________.

I«ê »í«e 3 Kæ ìtumö àwæn örö wönyí sílë ní èdèe Yorùbá. Write down the meanings of these words in Yorùbá.

1. ayálégbé 2. nõkan ösìn 3. yàrá ìdáná 4. ilé ìyàgbê 5. ìkangun ilé

I«ê »í«e 4 Ó kàn ê. Sæ fún wa nípa iléè bàbáà r÷.

Page 30: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 256 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 5 Ní méjì-méjì, ÷ sæ fùn araa yín nípa ibi tí ë ñ gbé. In pairs, tell your friend about where you live (your dorm, apartment etc)

Örö àdásæ (Monologue)

Tósìn ñ sörö nípa yàráa rë

Nínúu yàráà mi, mo ní ibùsùn, ìrörí, àga, tábìlì ìkàwé, kôbôödù ìká«æsí, rédíò alágbèéká kékeré kan, kápêëti (÷ní àtêëká) àti bêë bêë læ. Ní pálö, àga onítìmùtìmù mêrin ni wôn wà níbë, t÷lifí«àn ñlá kan, rédíò ñlá kan, aago ñlá kan àti orí«irí«i àwòrán ara ògiri ni ó wa níbë pëlú. Sítóòfù onígáàsì àti sítóòfù onik÷rosíìnì wà nínúu ilé ìdáná. Bê÷ náà sì ni fìríìjì àti síìnkì. Ohún-èlò ìdáná orí«irí«i bíi àwo, abô, ìkòkò, «íbí, fôökì àti öb÷ náà sì wà níbë. Ëræ omi, tôöbù, «áwà, síìnkì, æ«÷ ìwë àti táwëëlì wà nínúu balùwë.

I«ê »í«e 6 Dáhùn àwæn ìbèérè wönyí. Answer the following questions.

1. Kí ni ó wà nínúu yàráaTósìn tí ó lè lò láti fi sùn? 2. Kí ni ó wà nínúu yàráaTósìn tí ó lè ká«æ sí? 3. Dárúkæ àwæn nõkan tí ó wà nínúu pálöæ Tósìn? 4. Dárúkæ àwæn nõkan tí ó wà nínú ilé ìdánáa Tósìn? 5. Níbo ni ó fêràn jù nípa ibi tí Tósìn ñ gbé?

I«ê »í«e 7 Sæ bêë ni tàbí bêë kô fún àwæn gbólóhùn wönyí. State whether the following sentences are true or false.

BÊË NI BÊË KÔ

1. Àwæn nõkan tí wôn «e pàtàkì wà ní yàráaTósìn. ☐ ☐

2. Tósìn máa ní àõfààní láti mæ ohun tó ñ læ láwùjæ. ☐ ☐

3. Tósìn máa ní àõfààní láti dáná ní ìgbàkúùgbà tí ó bá wù ú. ☐ ☐

4. YàráaTósìn dára láti gbé. ☐ ☐

5. Tósìn kò ní láti læ pæn omi ni ibòmíràn kí ó tó lè wë. ☐ ☐

Page 31: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 257 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 8 Ó kàn ê. »e àpèjúwe yàráà r÷. Now it’s your turn. Describe your room.

Örö àdásæ (Monologue) Jídé ñ sörö nípa ilé-ìwë÷ rë. (Jídé is talking about his bathroom.)

ILÉ-ÌWË¿ MI (MY BATHROOM)

Nínú ilé-ìwë÷ mi‚ orí«irí«i nõkan ni mo ní níbë bíi ìpara‚ ìparun‚ ìyarun‚ æ«÷ ìfæyín‚ æ«÷ ìwë‚ æ«÷ ìfæwô‚ a«æ ìnura‚ omi tútù‚ omi gbígbóná‚ búrôö«ì‚ kábínêëtì‚ kànhìnkànhìn‚ tí«ù‚ àti àwæn nõkan mìíràn. Ní gêlê tí mo bá ti wæ inú ilé-ìwëë mi‚ búrôö«ì mi ni mo kôkô máa ñ kì môlë tí mà á fi æ«÷ ìfæyín sí i. Mo bërë sí fæ ÷nu læ nìy÷n. Lêyìn öpölöpö ì«êjú‚ mà á bu omi yálà tútú tàbí gbígbóná láti fi fæ ÷nuù mi mô. Àwæn Yorùbá ní ìgbàgbô pé omi tútú máa ñ jê kí ara nà dáadáa‚ àmô tí òtútù bá mú jù‚ omi gbígbóná ni mo máa ñ fi í wë pëlú æ«÷ àti kànhìnkànhìn ní àárö kí gbogbo ìdötí ara le bá omi læ. Mo máa fi ìpara àti ìparun ra ara àti irunùn mi. Tí mo bá ti wë tàn máa sì yarun pëlú. Lêyìn gbogbo èyí‚ háà! Oúnj÷ yá láti j÷ nìy÷n!

I«ê »í«e 9 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí. Answer the following questions.

1. Kí ni Jídé máa ñ kôkô «e tí ó bá ti jí? 2. »é ìwæ mö bôyá Jídé máa ñ wë tí ó bá ti jí? Kæ gbólóhùn kan jade láti inú àyækà yìí láti fi

gbe ìdáhùn r÷ lêsë. 3. Õjê o rò pé Jídé ní ìmö-tótó? Kí ni o fi dá ìwæ lójú? 4. Kí ni àwæn nõkan tí ó «e pàtàkì tí o rò pé ó y÷ kí ó wà nínúu ilé-ìwë÷ Jídé gêgê bí o «e rí i

kà nínúu ayækà náà? 5. Õjê o rò pé Jídé fêràn oúnj÷? Má «àì fi gbólóhùn kan gbe ìdáhùn r÷ lêsë.

Page 32: Chapter 10 - Orí K÷wàá HOME SWEET HOME! · omi tútù cold water æ«÷ ìfæwô hand soap æ«÷ ìfærun («ampú) shampoo æ«÷ ìwë bath soap Verb kórira to dislike Verb

Orí K÷wàá (Chapter 10) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yé Mi Page 258 CC – 2011 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 10 Dáhùn àwon ìbéèrè wönyí. Answer the following questions.

Bí àp÷÷r÷:

Kí ni a fi ñ nura?

A«æ ínura tabí táwêëli ni a fi ñ nura

1. Kí ni a fi ñ wë?

2. Kí ni a fi ñ fæ ÷nu?

3. Kí ni a fi ñ wo ojú?

4. Kí ni a fi ñ ya irun?

5. Kí ni a fi ñ fæ eyín?

6. Kí ni a fi ñ nu æwô

7. Kí ni àwæn ækùnrin fi ñ fá irùgbön

8. Kí ni a fi ñ fæ irun?

9. Kí ni àwæn obìnrin fi ñ kun ojú?

10. Kí ni a fi ñ pa ara?